Association of Nigerian Women Entrepreneurs and Professionals

Covid-19 Vaccine Confidence Survey

Choose Your Preferred Language To Fill Form

Ẹyin ololufẹ ibasepọ,

Bi ẹ se mọ pe Covid 19 ti pa ọpọlọpọ to ju miliọnu kan lọ ni ilu Amẹrika ati eyi ti o si ti ni ipa ninu eniyan bi miliọnu mẹtalelọgọrin. O si mu ki aye soro fun ẹbi ti olori ile ibẹ jẹ ẹni ti o ni Arun Covid 19.

ANWEP-USA ni ibasepọ pẹlu CDC – (CENTERS FOR DISEASES CONTROL) Agbo ile idena  Arun, ti fẹ, fi tifẹtifẹ gbera dide lati mu ojutu ati jẹ akọni fun ikoju Arun Covid 19. Wọn si fẹ  iranlọwọ nipa gbigba alaye ti yo mu ilera ba awujọ wa.

Ẹjọwọ ẹ dahun ibere kekere yi

Iwadi isẹju mẹwa pere lati mọ bi o ba ti gba Abẹrẹ Ajẹsara Covid 19, bi bẹ kọ, kini o n da ọ duro lati gba, tabi ọna wo lati lese iranlọwọ?

Gbogbo idahun ibeere ni a o gbasile ni ailorukọ, nitorina mase foya lati pese esi ootọ. Idahun rẹ yio se iranlọwọ lati se agbekalẹ eto, ti yio ri daju pe awọn ọmọ ilẹ Afrika ti o tẹdo si Texas yio gba Abẹrẹ Ajẹsara lati koju Arun Covid 19.

//